Kí ni ìwọ yóò yàwòràn rẹ̀ lónìí?
Ṣe àwọn ọ̀rọ̀ àfiránṣẹ̀ ojúlà, fídíò, àfihàn iṣẹ́, àti ju bẹ́ẹ̀ lọ ti AI ró lágbára pẹ̀lú Canva.
Àwọn irinṣẹ́ láti ró tí o dára jù lágbára
Yí ìjíròrò padà sí ìṣẹ̀dá pẹ̀lú AI Canva 2.0
Pa àwọn fọ́tò rẹ́ pẹ̀lú Ìpa ǹkan rẹ́ Ìdán
Ṣẹ̀gbéga kíkọ rẹ pẹ̀lú Ìkọ Idán
Yi àwòrán rẹ si àlàkalẹ̀ tó ṣe e ṣàtúnṣe pẹ̀lú Àwọn Ìpele Idán
Ṣẹda àwọn àfihàn iṣẹ́ tí ń bániṣe àti mú ìmísí wá
Wa ojúlówó àwòṣeàfihàn iṣẹ́ rẹ
Dúró lórí búrándì pẹ̀lú Ibi àkọ́jọpọ̀ ohun èlò ìyàwòrán
Mú àwọn àfihàn iṣẹ́ wa sáàyè nípa lílo àwòrán abẹ̀mí
Ṣẹ̀dá fídíò rẹ tókàn láìní ìnira pẹ̀lú àwọn àwòṣe tó gbajúmọ̀
Yọ àwọn àgbétẹ́lẹ̀ àwòrán àti fídíò kúdò ní ṣíra tẹ kan
Jẹ́ kí èyíkèyí fótò hàn dáradára pẹ̀lú Image Upscaler
Ṣe ìsọ̀díwọ̀n ìyàwòrán kan kíákíá fún èyíkèyí àwọn ìkànnì
Pẹ̀lú ìrọrùn, yí àwọn kílípù rẹ si àkóónú pẹ̀lú alátúnse fídíò wa
Gbogbo àwọn àwòṣe fídíò rẹ ní ojú kan
Àwọn fídíò ìpamọ́ tí ojúlówó sítúdíò fún gbogbo iṣẹ́ àkànṣe
Mú àjọṣẹpọ̀ pọ̀ si pẹ̀lú àwọn àkọlé ti AI tí o lágbára.
Yí àwọn àbá padà sí àwọn ìtẹ̀jáde tó ní ìpele gíga pẹ̀lú Àtẹ̀jáde Ibi-ìtajà.
Ṣàtúnṣe àwọn yàwòrán kíákíá fún èyíkèyí àtẹ̀jáde
Yàwòrán, kí o sì tẹ àwọn ìfìwépèni fún èyíkèyí ayẹyẹ.
Mú àsìkò eré wá sí ààyè pẹ̀lú àwọn àwòṣe Ìtàn Ìṣeré Disney Pixar
Gbogbo àwọn irinṣẹ́ náà. Gbogbo rẹ́ ní ojú kan.
Pàdé Ibi iṣẹ́ Àfojúrí
Gbogbo àwọn ààtò iṣẹ́ rẹ yòó wà ní ojú kan fún ìsẹ̀dá ìrọ̀run tí ó fi mọ́ ìfọwọ́sowọ́pọ̀, tí ìmọ̀-àtọwọ́dá AI ṣagbátẹrù rẹ.
Ṣàfihàn pẹ̀lú ìnípa
Ṣàtúnsọ lórúkọ àwọn àfihàn iṣẹ́ tó ní àwọn àwòrán àràọ̀tọ̀, ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ọlọ́gbọ́n àti àwọn irinṣẹ́ tí AI ṣagbátẹrù rẹ.
Àwọn àwòṣe fún èyíkèyí ohunkóhum
Bẹ̀rẹ̀ àtòkọ àwòṣe
Ìpari àtòkọ àwòṣe